Akekoo Hub – Yorùbá Sound Dictionary
Useful Phrases
Káàbọ̀!
Ẹ káàbọ̀!
Welcome
O ṣé
Ẹ ṣé
Thank You
Ó dàbọ̀
Goodbye
Kín ni orúkọ ẹ?
Kín ni orúkọ yín?
What is your name?
Orúkọ mi ni ___
My name is ___
Ọmọ ọdún mélòó ni ẹ́?
Ọmọ ọdún mélòó ni yín?
How old are you?
Ọmọ ọdún ______ ni mí.
I am ____ years old
Báwo ni?
How are you?
Kí ló ń ṣẹlẹ̀?
What’s up?
Dáadáa la wà
We are okay
Dáadáa ni mo wà.
I am great
Mo wà ní àlàáfíà.
I’m well
Kì lo fẹ́ ?
Kì lẹ fẹ́ ?
What do you want?
Mo fẹ́ ____
A fẹ́ _____
I want______
We want____
Kì lo fẹ́ jẹ ?
Kì lẹ fẹ́ ?
What do you want to eat?
Mo fẹ́ jẹ____
A fẹ́ jẹ_____
I want to eat___
We want to eat___
Bẹ́ẹ̀ ni
Yes
Bẹ́ẹ̀ kọ́ / Rárá / Irọ́
No
Bóyá
Maybe
N kò mò
I don't know
Ṣé ó yé ọ?
Ṣé ó yé yín?
Do you understand?
Ó yé mí
I understand?
Kò yé mí
I don’t understand
Mo gbàgbé / Mo ti gbàgbé
I forgot / I have forgotten
Ṣé ó rántí?
Ṣé ẹ rántí?
Can you remember?
Mi ò rántí
I can’t remember.
Mo rántí
I remember.