Akekoo Hub – Yorùbá Sound Dictionary

Ìkíni – Greetings (contraction)

Kàárọ̀ – Ẹ kàárọ̀

 Good morning

Káàsán – Ẹ káàsán

Good Afternoon

Kúrọ̀lẹ́ – Ẹ kúrọ̀lẹ́

Good evening

Early evening (4pm-6pm)

Kaalẹ́ – Ẹ káalẹ́

Good evening

Late evening (6pm and up)

Káàbọ̀ – Ẹ káàbọ̀

Welcome

Káàbọ̀ – Ẹ káàbọ̀

Welcome